Ẹsira 8:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo sọ fún wọn pé, “A yà yín ati gbogbo nǹkan wọnyi sí mímọ́ fún OLUWA. Fadaka ati wúrà jẹ́ ọrẹ àtinúwá fún OLUWA Ọlọrun àwọn baba yín.

Ẹsira 8

Ẹsira 8:21-29