Ẹsira 7:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹsira bá dáhùn pé, “Ìyìn ni fún OLUWA, Ọlọrun àwọn baba wa, tí ó fi sí ọba lọ́kàn láti ṣe ọ̀ṣọ́ sí tẹmpili Ọlọrun ní Jerusalẹmu,

Ẹsira 7

Ẹsira 7:26-28