Ẹsira 7:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí o bá fẹ́ ohunkohun sí i fún lílò ninu Tẹmpili Ọlọrun rẹ, gbà á ninu ilé ìṣúra ọba.

Ẹsira 7

Ẹsira 7:12-27