Ẹsira 7:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Fadaka ati wúrà tí ó bá ṣẹ́kù, ìwọ ati àwọn eniyan rẹ, ẹ lò ó bí ó ti yẹ lójú yín ati gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ Ọlọrun yín.

Ẹsira 7

Ẹsira 7:8-19