Ẹsira 7:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Ẹsira fi gbogbo ọkàn rẹ̀ sí kíkọ́ òfin OLUWA, ati pípa á mọ́ ati kíkọ́ gbogbo àwọn ọmọ Israẹli.

Ẹsira 7

Ẹsira 7:6-20