Ẹsira 6:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ní ìlú Ekibatana, olú-ìlú tí ó wà ní agbègbè Media, ni wọ́n ti rí ìwé àkọsílẹ̀ kan tí ó kà báyìí pé:

Ẹsira 6

Ẹsira 6:1-9