Ẹsira 6:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí wọ́n baà lè rú ẹbọ tí yóo jẹ́ ìtẹ́wọ́gbà sí Ọlọrun ọ̀run, kí wọ́n sì lè máa gbadura ibukun fún èmi ati àwọn ọmọ mi.

Ẹsira 6

Ẹsira 6:5-20