Ẹsira 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“A bèèrè lọ́wọ́ àwọn àgbààgbà wọn pé, ta ló fun wọn láṣẹ láti tún tẹmpili yìí kọ́ ati láti dá àwọn nǹkan inú rẹ̀ pada sibẹ.

Ẹsira 5

Ẹsira 5:1-16