Ẹsira 4:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ pàṣẹ pé kí wọ́n dáwọ́ iṣẹ́ náà dúró títí wọn yóo fi gbọ́ àṣẹ mìíràn láti ọ̀dọ̀ mi.

Ẹsira 4

Ẹsira 4:19-23