Ẹsira 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Kabiyesi, tí wọ́n bá fi lè kọ́ ìlú náà parí, tí wọ́n sì parí odi rẹ̀, wọn kò ní san owó ìṣákọ́lẹ̀ mọ́. Eléyìí yóo sì dín owó tí ń wọ àpò ọba kù.

Ẹsira 4

Ẹsira 4:12-20