Ẹsira 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà ti àwọn ọ̀tá Juda ati ti Bẹnjamini gbọ́ pé àwọn tí wọ́n ti ìgbèkùn dé ti bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ ilé OLUWA Ọlọrun Israẹli,

Ẹsira 4

Ẹsira 4:1-3