Ẹsira 2:68 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n dé ilé OLUWA ní Jerusalẹmu, díẹ̀ ninu àwọn olórí ìdílé náà fi ọrẹ àtinúwá sílẹ̀ láti tún ilé Ọlọrun kọ́ sí ààyè rẹ̀.

Ẹsira 2

Ẹsira 2:58-70