Ẹsira 2:64 BIBELI MIMỌ (BM)

Àpapọ̀ gbogbo àwọn tí wọ́n ti oko ẹrú dé jẹ́ ọ̀kẹ́ meji ó lé ẹgbaa, ó lé ọtalelọọdunrun (42,360).

Ẹsira 2

Ẹsira 2:56-65