Ẹsira 2:60 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Delaaya, àwọn ọmọ Tobaya, ati àwọn ọmọ Nekoda. Gbogbo wọn jẹ́ ọtalelẹgbẹta ó dín mẹjọ (652).

Ẹsira 2

Ẹsira 2:59-66