Ẹsira 2:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Iye àwọn ọmọ àwọn aṣọ́nà:àwọn ọmọ Ṣalumu ati àwọn ọmọ Ateri, àwọn ọmọ Talimoni ati àwọn ọmọ Akubu; àwọn ọmọ Hatita ati àwọn ọmọ Ṣobai jẹ́ mọkandínlogoje (139)

Ẹsira 2

Ẹsira 2:37-48