Ẹsira 2:18-22 BIBELI MIMỌ (BM)

18. Àwọn ọmọ Jora jẹ́ aadọfa ó lé meji (112)

19. Àwọn ọmọ Haṣumu jẹ́ igba ó lé mẹtalelogun (223)

20. Àwọn ọmọ Gibari jẹ́ marundinlọgọrun-un

21. Àwọn ọmọ Bẹtilẹhẹmu jẹ́ mẹtalelọgọfa (123)

22. Àwọn eniyan Netofa jẹ́ mẹrindinlọgọta

Ẹsira 2