Ẹsira 2:16-18 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Àwọn ọmọ Ateri láti inú ìran Hesekaya jẹ́ mejidinlọgọrun-un

17. Àwọn ọmọ Besai jẹ́ ọọdunrun ó lé mẹtalelogun (323)

18. Àwọn ọmọ Jora jẹ́ aadọfa ó lé meji (112)

Ẹsira 2