Ẹsira 10:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Orúkọ àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n fẹ́ obinrin àjèjì nìwọ̀nyí:Ninu ìdílé Paroṣi: Ramaya, Isaya, ati Malikija; Mijamini, Eleasari, Haṣabaya ati Benaaya.

Ẹsira 10

Ẹsira 10:21-33