Ẹsira 10:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ṣe ìpinnu láti kọ àwọn aya wọn sílẹ̀, wọ́n sì fi àgbò kọ̀ọ̀kan rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ wọn.

Ẹsira 10

Ẹsira 10:11-29