Ẹsira 10:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí yóo fi di ọjọ́ kinni oṣù kinni, wọ́n ti parí ìwádìí lórí gbogbo àwọn tí wọ́n fẹ́ obinrin àjèjì.

Ẹsira 10

Ẹsira 10:16-27