Ẹsira 1:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Kirusi ọba fún Mitiredati, akápò ìjọba rẹ̀ ní àṣẹ láti kó wọn síta, ó sì kà wọ́n ní ọ̀kọ̀ọ̀kan fún Ṣeṣibasari, olórí ẹ̀yà Juda.

Ẹsira 1

Ẹsira 1:1-10