Ẹkún Jeremaya 5:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn baba wa ni wọ́n dẹ́ṣẹ̀, àwọn sì ti kú,ṣugbọn àwa ni à ń jìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn.

Ẹkún Jeremaya 5

Ẹkún Jeremaya 5:3-11