Ẹkún Jeremaya 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nisinsinyii, ojú wọn dúdú ju èédú lọ,kò sí ẹni tí ó dá wọn mọ̀ láàrin ìgboro,awọ ara wọn ti hunjọ lórí egungun wọn,wọ́n wá gbẹ bí igi.

Ẹkún Jeremaya 4

Ẹkún Jeremaya 4:1-18