Ẹkún Jeremaya 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ajáko a máa fún àwọn ọmọ wọn lọ́mú.Ṣugbọn àwọn eniyan mi ti di ìkà,bí ògòǹgò inú aṣálẹ̀.

Ẹkún Jeremaya 4

Ẹkún Jeremaya 4:1-8