Ẹkún Jeremaya 4:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan ń ṣọ́ ìrìn ẹsẹ̀ wa,tóbẹ́ẹ̀ tí a kò lè rìn gaara ní ìgboro.Ìparun wa súnmọ́lé,ọjọ́ ayé wa ti níye,nítorí ìparun wa ti dé.

Ẹkún Jeremaya 4

Ẹkún Jeremaya 4:15-22