Ẹkún Jeremaya 4:16 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA fúnrarẹ̀ ti tú wọn ká,kò sì ní náání wọn mọ́.Kò ní bọlá fún àwọn alufaa wọn,kò sì ní fi ojurere wo àwọn àgbààgbà.

Ẹkún Jeremaya 4

Ẹkún Jeremaya 4:7-22