Ẹkún Jeremaya 3:65-66 BIBELI MIMỌ (BM) Jẹ́ kí ojú inú wọn fọ́,kí ègún rẹ sì wà lórí wọn. Fi ibinu lépa wọn, OLUWA,sì pa wọ́n