Ẹkún Jeremaya 3:64-66 BIBELI MIMỌ (BM)

64. “O óo san ẹ̀san fún wọn, OLUWA,gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ wọn.

65. Jẹ́ kí ojú inú wọn fọ́,kí ègún rẹ sì wà lórí wọn.

66. Fi ibinu lépa wọn, OLUWA,sì pa wọ́n run láyé yìí.”

Ẹkún Jeremaya 3