Ẹkún Jeremaya 3:56 BIBELI MIMỌ (BM)

O gbọ́ ẹ̀bẹ̀ tí mò ń bẹ̀ pé,‘Má ṣe di etí rẹ sí igbe tí mò ń ké fún ìrànlọ́wọ́.’

Ẹkún Jeremaya 3

Ẹkún Jeremaya 3:49-60