Ẹkún Jeremaya 3:4-7 BIBELI MIMỌ (BM)

4. Ó ti jẹ́ kí n rù kan egungun,ó sì ti fọ́ egungun mi.

5. Ó dótì mí,ó fi ìbànújẹ́ ati ìṣẹ́ yí mi káàkiri.

6. Ó fi mí sinu òkùnkùnbí òkú tí ó ti kú láti ọjọ́ pípẹ́.

7. Ó mọ odi yí mi ká,ó sì fi ẹ̀wọ̀n wúwo dè mí,kí n má baà lè sálọ.

Ẹkún Jeremaya 3