Ẹkún Jeremaya 3:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó tilẹ̀ mú kí ìbànújẹ́ dé bá wa,yóo ṣàánú wa, yóo tù wá ninu,gẹ́gẹ́ bí ọpọlọpọ ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀.

Ẹkún Jeremaya 3

Ẹkún Jeremaya 3:29-34