Ẹkún Jeremaya 3:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ó fi ọwọ́ lẹ́rán, kí ó dákẹ́, kí ó sì máa wòye,nítorí Ọlọrun ni ó gbé àjàgà náà kọ́ ọ lọ́rùn.

Ẹkún Jeremaya 3

Ẹkún Jeremaya 3:20-29