Ẹkún Jeremaya 2:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kẹ́ ọfà rẹ̀ bí ọ̀tá,ó múra bí aninilára.Gbogbo ògo wa ló parun lójú wa,ó sì tú ibinu rẹ̀ jáde bí iná, ninu àgọ́ Sioni.

Ẹkún Jeremaya 2

Ẹkún Jeremaya 2:2-7