Ẹkún Jeremaya 2:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kígbe sí OLUWA,ẹ̀yin ará Sioni!Ẹ jẹ́ kí omi máa dà lójú yín pòròpòrò tọ̀sán-tòru;ẹ má sinmi,ẹ má sì jẹ́ kí oorun kùn yín.

Ẹkún Jeremaya 2

Ẹkún Jeremaya 2:14-21