Ẹkún Jeremaya 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹkún sísun ti sọ ojú mi di bàìbàì,ìdààmú bá ọkàn mi;ìbànújẹ́ sì mú kí ó rẹ̀wẹ̀sìnítorí ìparun àwọn eniyan mi,nítorí pé àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ati àwọn ọmọ ọwọ́ ń dákú lójú pópó láàrin ìlú.

Ẹkún Jeremaya 2

Ẹkún Jeremaya 2:4-14