Ẹkún Jeremaya 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ògo Jerusalẹmu ti fò lọ kúrò lára rẹ̀,àwọn olórí rẹ̀ dàbí àgbọ̀nríntí kò rí koríko tútù jẹ;agbára kò sí fún wọn mọ́,wọ́n ń sálọ níwájú àwọn tí ń lé wọn.

Ẹkún Jeremaya 1

Ẹkún Jeremaya 1:1-10