Ẹkún Jeremaya 1:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọ̀nà tó lọ sí Sioni ń ṣe ìdárò,nítorí kò sí ẹni tí ó ń gba ibẹ̀ lọsíbi àwọn àjọ̀dún tí a yà sọ́tọ̀ mọ́.Àwọn ẹnubodè rẹ̀ ti di ahoro,àwọn alufaa rẹ̀ sì ń kẹ́dùn.Wọ́n ń pọ́n àwọn ọmọbinrin rẹ̀ lójú,òun pàápàá sì ń joró lọpọlọpọ.

Ẹkún Jeremaya 1

Ẹkún Jeremaya 1:1-13