Ẹkún Jeremaya 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ń sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn lóru,omijé ń dà lójú rẹ̀,kò sì sí ẹni tí yóo tù ú ninu, láàrin àwọn alajọṣepọ rẹ̀.Gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ti dà á,wọ́n dìtẹ̀ mọ́ ọn,wọ́n sì di ọ̀tá rẹ̀.

Ẹkún Jeremaya 1

Ẹkún Jeremaya 1:1-3