Gbogbo àwọn eniyan rẹ̀ ń kérorabí wọ́n ti ń wá oúnjẹ;wọ́n ń fi ìṣúra wọn ṣe pàṣípààrọ̀ fún oúnjẹkí wọ́n baà lè lágbára.Jerusalẹmu ń sunkún pé,“Bojúwò mí, OLUWA,nítorí pé mo di ẹni ẹ̀gàn.”