Ẹkisodu 9:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Farao bá ranṣẹ lọ wo àwọn ẹran ọ̀sìn àwọn ọmọ Israẹli, ó sì rí i pé ẹyọ kan kò kú ninu wọn. Sibẹsibẹ ọkàn Farao le, kò sì jẹ́ kí àwọn eniyan náà lọ.

Ẹkisodu 9

Ẹkisodu 9:1-14