Ẹkisodu 9:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí Farao rí i pé òjò ti dá, ati pé yìnyín ati ààrá ti dáwọ́ dúró, ó tún dẹ́ṣẹ̀, ọkàn rẹ̀ tún le, ati ti àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀.

Ẹkisodu 9

Ẹkisodu 9:33-35