Ẹkisodu 9:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn tí wọn kò ka ọ̀rọ̀ OLUWA sí fi àwọn ẹrú ati àwọn ohun ọ̀sìn wọn sílẹ̀ ninu pápá.

Ẹkisodu 9

Ẹkisodu 9:15-29