Ẹkisodu 8:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn pidánpidán náà gbìyànjú láti mú kí iná jáde pẹlu ọgbọ́n idán wọn, ṣugbọn wọn kò lè ṣe é. Iná bo gbogbo eniyan ati àwọn ẹranko.

Ẹkisodu 8

Ẹkisodu 8:8-23