Ẹkisodu 8:13 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ṣe ohun tí Mose fi adura bèèrè, àwọn ọ̀pọ̀lọ́ tí wọ́n wà ninu gbogbo ilé, ati ní àgbàlá, ati ní gbogbo oko sì kú.

Ẹkisodu 8

Ẹkisodu 8:12-14