Ẹkisodu 7:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni n óo nawọ́ ìyà sí Ijipti, n óo sì kó àwọn ọmọ Israẹli, ìjọ eniyan mi, jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti pẹlu iṣẹ́ ìyanu ati ìdájọ́ ńlá.

Ẹkisodu 7

Ẹkisodu 7:1-13