Ẹkisodu 7:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ará Ijipti bẹ̀rẹ̀ sí gbẹ́lẹ̀ káàkiri yíká odò Naili, pé bóyá wọn á jẹ́ rí omi mímu nítorí pé wọn kò lè mu omi odò Naili mọ́.

Ẹkisodu 7

Ẹkisodu 7:22-24