Ẹkisodu 7:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹja inú odò náà yóo kú, odò náà yóo sì máa rùn, tóbẹ́ẹ̀ tí àwọn ará Ijipti kò ní lè mu omi inú rẹ̀ mọ́.’ ”

Ẹkisodu 7

Ẹkisodu 7:16-24