Ẹkisodu 6:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Eleasari ọmọ Aaroni fẹ́ ọ̀kan ninu àwọn ọmọbinrin Putieli; ó sì bí Finehasi fún un; àwọn ni olórí àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi.

Ẹkisodu 6

Ẹkisodu 6:17-30