Ẹkisodu 5:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ọba Ijipti dá wọn lóhùn pé, “Ìwọ Mose ati ìwọ Aaroni, kí ló dé tí ẹ fi kó àwọn eniyan wọnyi kúrò lẹ́nu iṣẹ́ wọn? Ẹ kó wọn pada kíákíá.”

Ẹkisodu 5

Ẹkisodu 5:3-6