Ẹkisodu 5:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọ́n fi ṣe olórí láàrin àwọn ọmọ Israẹli bá ké tọ Farao lọ, wọ́n ní, “Kí ló dé tí o fi ń ṣe báyìí sí àwa iranṣẹ rẹ?

Ẹkisodu 5

Ẹkisodu 5:10-16